Olorun Ni Yio Ma Je by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Tope Alabi

Olorun Ni Yio Ma Je by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Olorun Ni Yio Ma Je by Tope Alabi Mp3 Download. Do you wish to download Olorun Ni Yio Ma Je By Tope Alabi for free? Then, you are going to find the download link here.

Our God is the same yesterday, today and forever. The God that reigneth superior in the old testament is still the One on throne up till date and no one can take the throne from Him. He is able, He is mighty, He is faithful. This song is part of the album Yes And Amen and was released 2019.

Download Here

Lyrics Olorun Ni Yio Ma Je By Tope Alabi Mp3 Music.

Olorun ni yio ma je
Olorun ni yio ma je
Lana loni lola o, titi de ayeraye
Olorun ni yio ma je

Olorun ni yio ma je (Olorun ni yio ma je)
Olorun ni yio ma je (titi lai, titi lai, titi lai, titi lai)
Lana loni lola o (Lana o),
Titi de ayeraye (Loni o)
Olorun ni yio ma je (Titi Aye… Titi Aye)

Alagbara ni ko se segun o
Ipa nla ni ko de le ku ooo
Aileyipada to la ye ni ikawo
Emi se’ba oluda orun o
(Emi se’ba oluda orun)

Olorun ni yio ma je (akoko nda olu nda aye)
Olorun ni yio ma je (patapata pira ogo nibi to pari si)
Lana loni lola o (patapata ola)
Titi de ayeraye
Olorun ni yio maje

Ailetuwa o ti wa ko to da orun
Tale ri ni ati titi loni
Eni ni igba ti o ni bere
Beni ko lopin
Mo juba akoda aye o
(Patapata ogo)

Olorun ni yio maje
(Eni lade to ti dade ka to d’aye)
Olorun ni yio ma je
(Eni lade to ti dade ka to da orun)
Lana loni lola o (Isaju Aye)
Titi de ayeraye (Isaju Orun)
Olorun ni yio ma je

Ko seni to da nigba toti njoba o
A o towo eda kan hun ade ori e
Akobi orun o
Olusa ju aiye de
Jehova emi se ba o (okankan oju awon agba lorun)

Olorun ni yio ma je (iriju oju awon angeli ojojumo)
Olorun ni yio ma je (iba eni ta won t’orun se ti won o dake)
Kosi ariyan jiyan lori gun merin orun ati aye
Ko ni sai je olorun mo
Eeeeh

Olorun ni yio ma je (iwo ni kan lo ma je olorun titi)
Olorun ni yio ma je (oti je olorun ko to da orun rara)
Ko si ariyan jiyan lori gun merin orun ati aye o
Ko ni sai je olorun mo (Iba o iba o)
Olorun ni yio ma je (emi seba oro kodo asiri aye)
Olorun ni yio ma je(asiri aye pelu orun, owo re ni kan lowa)
Lana loni lola o, titi de ayeraye
Olorun ni yio ma je (akoko ati eyin)

escort