Odara Ni Ife by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics) – Insurance Blog
Connect with us

Insurance Blog

Advertising

Odara Ni Ife by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Advertising

Gospel Lyrics

Odara Ni Ife by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Odara Ni Ife by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Odara Ni Ife by Tope Alabi Mp3 Download. Do you wish to download Odara Ni Ife By Tope Alabi for free? Then, you are going to find the download link here.

Advertising

All that breathes praise God, Give thanks unto His Holy Name, Praise Him the way it ought to be because He is the King of kings, The Lord of lords, the One who created you and I. We have come to give glory to you Lord, accept our offering of praise. This song is part of the album Oruko Tuntun and was released 2014.

Download Here

Advertising

Lyrics Odara Ni Ife By Tope Alabi Mp3 Music.

E fi’ba fun Un, e yin I o
Awon angeli, won n yi ite Re ka
Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye
E fi’ba fun Un, e yin I o
Awon angeli, won n yi ite Re ka
Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye
K’orin tuntun s’Oluwa iwo okan mi
E ma yo n’nu Oluwa eyin olododo
Nitori iyin ye fun Oluwa
E fi duru yin Oluwa t’ohun t’eelo orin
K’orin naa s’oke kikan k’aye ko gbo o
Nitori ile aye kun f’aanu Re
E fi’ba fun Un, e yin I o
Awon angeli, won n yi ite Re ka
Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye
Emi t’a dalarr ti a dariji
Emi t’Oluwa gba la, t’O se’gun fun
Okan mi k’orin yin Oga ogo
Awon angeli juba Re lojoojo
Agbaagba lorun f’iba yi ite Re ka
Pipe lo je ogo, lailakawe
E fi’ba fun Un, e yin I o
Awon angeli, won n yi ite Re ka
Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye
Mo f’eru gbe E ga, mo yin Oga ogo
O so ibu omi po, O gba okun jo
O s’oro, o si ti se mo yin O, Oluwa
E fi’ba fun Un, e yin I o
Awon angeli, won n yi ite Re ka
Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye
Didara ni ike, didara laabo
Didara ni ife, didara laabo
O po loore, O po ni’bukun o
Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo
Didara ni ike, didara laabo
Didara ni ife, didara laabo
O po loore, O po ni’bukun o
Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo
Ninu opo ife lo ragabo mi
Oore ofe Re ni mo n je
Ibukun Re to po, lo je k’emi po
Ninu ogo Re lokan mi n yo
Ohun gbogbo lO fi se ‘ke mi
Oba Onike, didara ni O
Didara ni ike, didara laabo
Didara ni ife, didara laabo
O po loore, O po ni’bukun o
Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo
O gba mi lowo ogun idile
Mariwo mi yo laarin igbago
Ogun ibi a ti bi d’atemole
Bi t’ota se po to won dake jeje
Apenimadani, didara ni O
Didara ni ike, didara laabo
Didara ni ife, didara laabo
O po loore, O po ni’bukun o
Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo
Alainironu o ni le dupe
Mi o ni ya ‘baramooreje
Olori ogun to f’ife ja ‘ja ikoro lori aye mi mo dupe
Ope mi ka sai gun lailopin titi laye
Aabo Re ti o ka lori ebi mi, komboki oore
Olorun to dara ni’ke, ige, Iwo ni maa sin o
Onife alailodiwon, Oloore mi O se
Didara ni ike, didara laabo
Didara ni ife, didara laabo
O po loore, O po ni’bukun o
Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo
Igba ti ogun dide ija oloro (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Igba ti eni a ro bi ore d’ota gbangba (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Igba eti ore gbo ogun, to f’ese fe (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Igba t’afeniferere o le rerin mo o (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Igba t’ebi wa ninu ipaya ogun oro o (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
T’abanijiroro o le beere eni mo, o ma se (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Olufe owon, Iwo nikan n mo ri o (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Igba ti ile kan roro, ti ito enu gbe lau (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Igba t’adura at’aawe di sisa, aisoje rara (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Igba yi mo wa r’arisa eniyan bi won ti n jehun eni t’on pani (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
As’ologo asun mala lakun nirin ajo aye yi (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Iwo to m’ooto oro, to mo ‘bere to mo ‘bi ti o pin si (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Arinurode Olumoran okan lo yo mi o Ose (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro)
Didara ni ike, didara laabo
Didara ni ife, didara laabo
O po loore, O po ni’bukun o
Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo
Didara ni ike, didara laabo
Didara ni ife, didara laabo
O po loore, O po ni’bukun o
Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo

Advertising
Click to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

More in Gospel Lyrics

To Top
escort