Mo Mope Mi Wa by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics) – Insurance Blog
Connect with us

Insurance Blog

Advertising

Mo Mope Mi Wa by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Advertising

Gospel Lyrics

Mo Mope Mi Wa by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Mo Mope Mi Wa by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Mo Mope Mi Wa by Tope Alabi Mp3 Download. Do you want to get a free copy of Mo Mope Mi Wa by Tope Alabi? Then, here’s where you’ll find the download link.

Advertising

All glory and praise must be given to the Lord Almighty, for He alone is worthy of our acclaim. Take a moment to praise God for everything He has done for you through the years. Sleeping and waking up as a gift for provision, guidance, and protection. Lord, we exalt Your name. This song was published in 2014 as part of the album Oruko Tuntun.

Download Here

Advertising

Lyrics Mo Mope Mi Wa By Tope Alabi Mp3 Music.

Oba to ku nitori mi, Oba taa pa nitori ese mi
Oba taa kan nitori mi mo mope mi wa fun o
Ada lebi iku, kemi le gba idalare
Ano ni pasan, kemi maba jiya
Oti kikan tomu, kinmaba jekoro ni
Atuto si lara, kemi le deni aponle
Ikoro irora toje nitori temi ni

Oba toku nitori mi, Oba taapa nitori ese mi
Oba taa kan nitori mi, mo mope mi wa fun o
La layi jebi ese, asi da lebi eshe
Isho owo ati ese re
Pelu oko egbe re Iya eshe mi ni
Ori ogo lofi dade egun fun emi o
Emi o mo oun ti moja mo o
Tofi se gbogbo iwonyi
Mo mope mi wa
Fun Oba to seyi fun mi

Oba to ku nitori mi, Oba ta pa nitori ese mi,
Oba taa kan nitori mi
Odo aguntan to k’eshe mi lo
Oloore to gbamila o
Ope aanu to po yi, mio riri
Mo wa pelu emi imore
Oba to di alaini kemi le d’loro
Mo mope mi wa fun o Baba
Iwo loje kopari
Ise ati Iya to tosi mi
Iwo loje ko tan aisan ti aarun ti nba ri
Iwo logba kokoro iku
Ati isa iboji ti nba wo oo
Oba to ra iye fun mi
Emi mo mope mi wa o oseee
Odo aguntan to ko ese mi lo
To somi di omo re
Mo mope mi wa fun o
Oba ayeraye to fi itere sile wa jiya fun emi
Mo mope mi wa fun oo
Owo elese ni ijoba orun
Kole daduro omase
Mo mope wa fun o
Oro ayeraye to deru nitori mi
Mo mope mi wa fun o
Iya toje lona agbelebu manigbagbe ni mo mon
Mo mope mi wa fun o
Oba to laye, to lorun To Wa di alai lara
Mo mope mi wa fun o
Oobo ogo re kale, owaye wa gbese mi wo ooo
Mo mope mi wa fun o
Oro ishura ogo iyebiye
Lofi fun mi loogun jè
Mo mope mi wa fun o
Iku E lori igi kafari lofi ra iye fun emi
Mo mope mi wa fun o
Ori ade ayeraye lofi tegun nitori mi o
Mo mope mi wa fun o
Emi mo riri ajinde re kemi maba shigbe ni
Mo mope mi wa fun o
Ore-ofe ti mo rigba lai dinyele loje nmope wa
Mo mope mi wa fun o
Oun gbogbo tose tose ose fun emi
Momope mi wa fun o
Bi mo legberun ahon
Ko to yin o olupinl’èshè
Momope mi wa fun o
Alasepe igba gbo
Olurapada ore tooto
Momope mi wa fun o
Momope mi wa f’eni
To femi lati odo inu
Momope mi wa fun o
Oba to feran mi ju enikeni lo ooo
Momope mi wa fun o
Ore airi oluto okan mi, mogbope ore de
Momope mi wa fun o
Ope ni mo wa da oo
Ope ni mo wa du lodo oloore mi
Momope mi wafun o

Advertising

Advertising
Click to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

More in Gospel Lyrics

To Top
escort