Ikoko Oga Ogo by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Ikoko Oga Ogo by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Ikoko Oga Ogo by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Ikoko Oga Ogo by Tope Alabi Mp3 Download. Do you wish to download Ikoko Oga Ogo By Tope Alabi for free? Then, you are going to find the download link here.

Those that endure and sit with Christ are the only ones that reap the fruits of the spirit. To be a disciple of Christ, we must be willing and be patient, wait on the Lord, He will answer your prayers in the appointed time. This song is part of the album Oruko Tuntun and was released 2014.

Download Here

Lyrics Ikoko Oga Ogo By Tope Alabi Mp3 Music.

Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio Ma gbe abe Ojiji Olodumare
Eni to joko nibikoko oga ogo
Ni yio Ma gbe abe Ojiji re
Ni yio Ma gbe abe Ojiji re

Ogun po oo ninu aiye
Awon to fori pamo sodo re nikan lo yege
Ibi nsele niwaju a wa o ni fara pa
Awa ngbe abe ojiji re

Iji nja losan loru
Owuro aiye fere lewu ju oru lo
Enito wa labe iye re nikan lo Le bo
Iso Olodumare nikan lodaju

Ogbon aiye ko kaiye jo Eeah!
Agbaraiye ko le kapa aiye
Aiye yiii bo eniyan aiye mole
Ipa toda aiye nikan lo ka

Oju eda ni tuuuuuu bi ti kiniun
Won se are won nibiiiiiii
Eda ti koro Ife tooooo
Beeni won dana yara won
Okan won gbe sirawon ooo
Abe ojiji nikan sa labo wa.

Olorun ni abo abo wa
Olorun ni asa asa wa
Awa niran ti n saferi re Olorun Isreli
Abiye apa re lawa gbekele

Olorun ni abo abo wa
Olorun ni asa asa wa
Awa niran ti n saferi re Olorun Jakobu
Abiye apa re lawa gbekele

Egberun yio subu ni eba otun
Egbarun ni apa osi wa
Orun ki yio pawa nigba osan
Tabi osupa aiye nigba oru
Kiki oju wa nikan lawa o Ma fi ri
Toragbe abe ojiji re

Awa lo pamo oo
Nigba ewu
Awa lo di lamure e e
Nigba ogun
Awa lo gbe sejika re
Nigba ile n mi
Awa lo fi sabe iye e
Nigba ofa mbo
Oruko oluwaa
Lagbokan wa le
Awa lo gbe eee
Labe ojiji re
Labe ojiji re

Awa lo n gbeeee
Labe ojiji oluwa
Awa lo fi sabe iye re
Abe ojiji re
Iwo to ngbe eee
Labe ojiji oluwa
Emi na gbeee
Labe ojiji re
Iwo to nfeee abo
Abe ojiji oluwa
Okan wa n gbeeee
Labe ojiji re
Awa lo n pamo o pamo
Labe ojiji oluwa
Awa lo ngbe eee
Abe ojiji re

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

escort

Adblock Detected

Please consider supporting us by disabling your ad blocker