Ayo by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Ayo by Tope Alabi Mp3 Download (Audio Lyrics)

Ayo by Tope Alabi Mp3 Download. Do you wish to download Ayo By Tope Alabi for free? Then, you are going to find the download link here.

All the years of your life, have you ever come across a friend that is willing to take a fall for you? Have you seen any friend that is willing to die for your sins, Jesus is that type of Friend. He is willing to carry your cross for you, he is willing to help you overcome your challenges, praise be to His holy name. This song is part of the album The Spirit Of Light and was released 2019.

Download Here

Lyrics Ayo By Tope Alabi Mp3 Music.

Aye le O ibosi O
Aye dorikodo, koyeni Mo
Ibo Lan lo eniyan osuni ye
Ibi Taba ma gba O koyeni Yan O.

Aye ma le ibosi oooo

Chrs: . Aye le O ibosi O
Aye dorikodo, koyeni Mo
Ibo Lan lo eniyan osuni ye
Ibi Taba ma gba O koyeni Yan O.

Eniyan E so fun mi nibo lanlo gan
Lomode at’agba awa deni tio gbonmo
Benikan ba se rere elomiran asebi
Onse mi on gba mi, Lan se dupe lowo Eni ton seni
Iberia Olorun kosi lokan aye Mo
Ibosi tan fele ke koje kami or Iya Ni
Nibo Lan re?

Chrs: Aye le O ibosi O
Aye dorikodo, koyeni Mo
Ibo Lan lo eniyan osuni ye
Ibi Taba ma gba O koyeni Yan O.

Aimoye igbeyawo Lori sanpan
Awon tofife bere won to donikorira
Abi osi nije tani Mo ri, Owo lonje Mo ba E tan
Ise sopo omobinrin dalagbere, okunrin njawo ka
Alafowofa Omo arise mase oku ole lo berebe
Baba ojomo loju Mo, otoju Suni,
Eje ka Tero ara wa pa
Abi bio se ma lo niyi o?
Aye O E Dami loun.

Chrs: Aye le O ibosi O
Aye dorikodo, koyeni Mo
Ibo Lan lo eniyan osuni ye
Ibi Taba ma gba O koyeni Yan O.

Opo Omo ti so obi donirewesi
Olukoni atakeko to dota ara won
Tori Aja to yo kole balai yo sere
Awon to wa kawe ti won orise se nko?
Opo agbanisise tio baba won sepo, konigbawon sise
Ese wan gori ese lo
Aye Jese tan O won tun gufe ese Jade
Iborisa ati Osho laye fin jeun
Ori olori apa alapa, odididi Omo tuntun aboyun dawati nigboro.
Eni towo moto elero jade Nile Ole mo pada wale Mo
Ibi ikoko ara won di fifa lo
Kaboni lowo iyen tun dogun
Kowa seni tose fokan tan mo
Ara Aye, igbawo lafe sheyi da O?
Egbo Na se samama wo Ni koyeniyan O

Aye le O ibosi O
Aye dorikodo, koyeni Mo
Ibo Lan lo eniyan osuni ye
Ibi Taba ma gba O koyeni Yan O.
Gbogbo ijo Olorun Ni gbogbo agbaye
Oro yi kanwa O
Ema laju sile Ki talubo okowo O
Eje Ka gbadura Bo senlo yi kosunwon
Wiwa alafia orile ede yi gbodo jewa logun
Gege bi onigbagbo, eje kaje apere rere
Awa loye ka bere
Gbo orile ede wa adura ko Mo E Lori
Kolorun gbase lowo esu ton fogun Mo O
Korire Ma gbabode kio gba atunse
Ile Nigeria bere si Ni se rere.

Gbo orile ede wa adura ko Mo E Lori
Kolorun gbase lowo esu ton fogun Mo O
Korire Ma gbabode kio gba atunse
Ile Nigeria bere si Ni se rere.

Ilu ibile mi Ibi agbe fori mi sole oya ma
Kore ran Mi O, orilede wa O bere sini se sere

Origun mererin Ile yi Ma gboro Oluwa, se rere eeeee

Ile Nigeria kio gba atunse.

Ese toti lere Sa Jesu darijini kire ma a Bo, sun wa bo

Orile ede wa O, bere sini se rere

Gbogbo eniyan to n be nibe emagba alafia Olorun ire kowole wa

Ile Nigeria kio gba atunse.

Gusu ariwa Ila orun iwo re, oya ma Ko ibodi Mo n so

Orile ede wa O, bere sini se rere.

Amin O Beni Kori se rere kenikeni mase Dio lowo (Amin)

Ile Nigeria kio gba atunse.

Leave a Comment